EWA EDE YORUBA

April 5, 2018 | Author: Anonymous | Category: Documents
Report this link


Description

EWA EDE YORUBA • • • • • • • • • • • • • • • • • • • • Mo tori imi, mo f’oko ha para. Mo tori ete, f’oro sikun bi agba. Mo tori ife, toro gigun emi feni odeje soju mi. Mo tori ola, mo ni baba, se ya ni wura baba ni digi. Mo tori ileke bawon mo run gungun wa ye. Mo tori ide wewe mo ni ponpolo itan. Mo tori nabi, yan re l’oko. Mo tori ote, mo legberin ore bi irinwo ba nbumi, kirinwo o yin mi. Mo tori ewe geru geru, mo bomi re kukundudu. Mo fe role, mo b’a ko. Mo tori oungbe, desun omi. Mo tori ale, mo sanwo osun oun t’adin. Mo d’emu l’ope tan, hun o lepo niinso. Mo tori ife aisetan, feni bi okan sa ya. Mo tori eja, mo gbokilo, Mo t’ori siso, hun o fale babaja oge. Mo tori aitete dele, mi o pada lona. Mo tori iwapele, hun o san be sun fapo rori. Mo wole abimi, mo somo loruko rere. Mo poruko rere mo, laibikita wura ohun fadaka. • • • • • Mo tori ile dida, mo pamule mo. Mo tori iri, hun o f’ito mo’le. Tori oju oro, ese eye o tomi. Mo tori ewa, mo gbosuba f’okin. Mo f’aigo, gbowo igunnu. OWE ATI ASAYAN ORO • • • • • • • • • Elulu to fa ojo, ori are re ni yo ro le. Ojo oganjo pelewu etu, ko se dele wi. Eje a maa wo bo, omode to so aja re ni ki tagba mase. Asebaje se bi toun la nwi, aseburuku eku aro fun. Ija ni topa, o pa p’ejo laije. Oye ni gbogbo ko yowo aro, ko ye atoole. Asin ku, eta ru hu, ikamudu nkofe, etu wipe n’kan n run. Omode to nfi igba muko, to ba dagba tan tagiri oni ka lenu mo. Oun ti ako je lenu ki run lona ofun eni. • • • • • • • • • • • • • • • • • • • • • Awodi ti nre ibara teletele, ti efufu sese wa ta ni di, ise ya nuhun. Ai foro sawani, oro o gbolu wa re lo. Ai pegbo legbo ile ka ma fi da ounje koje. Aka re o si ra e ka. Afoju ko mo poun o fo awo. Ologuna kankiirin leti omi. Okan roro nru, o ja efon lekanna. Aki soro ori bibe loju omode, lohun, lorun ni yoo ma wo ni. Nitori aja ti ode, ni aki fi ka tile leyin. Nijo okere ti nse epo, ko kun ata. Asoro safun bi iso inu eku. Ko sokunrin to fe fi elede inu oke saya, Elede inu oke- Obun. Eni ti o loyun Fulani, funfun ni o fibi. Bi ti nse o ni nse mi o ale inu ireke. Eniyan o le gogogo ko pe oko nja oun o da. O so aake sedun edun lo aake si lo, ateru atedun wo ko ra. Bi o laya o se ka, bi o ranti iku Gaa ko s’oto. Iya o to ya afadapakun, ikun wo gbo ada fo lo. Gambari o je die lobi, keyin o to pon. Omode ti o ba gbe enu agba sonu, bi won ba roko, won ki le ro d’ale. Ode to ba fe perin ko toju egbe, Eyi to fee pefon, ko toju ajabo, Eni ti o fe pa turuku, ko ma sa fira ojugun. • • • • Eje komo o yagbe tan ke to nudie. Enikan soso ko le gbedo ti nsan Oju oro ni koni jese eye o teju omi. Baale fe dajo ogun, oun wo taara ile, Agbebo fe ja, tawan omo re lo nwo. Obe ki jin ni ikun agba, inu to ba gbomo yoo gboro. Bomode bas u imi ki imi, kafi ewe esisi nu idi re. Ekan lagaba bi o ba kanni, koni yo iwo. Seran seran yoo leni ti jewo fun. Eni na ajanaku lada gbiyanju aje, erin ni ko wo fun. Eyan meji ni jebi okoo, eniti oya ti ko san ati eni ti ko le y’afi re. Kakiri la segi, oju kan laa di. Eni ti o ba mo nkan pamo, ki o ranti eni to mo wa. Alo ni ti ahun, abo ni ti ana re. Mi o yo, ebi o pami, ko’je a mo nti eledumare o se fun ni. Ayangbe aja dun, nkankan na lasa maje. Alabahun bokele, omo re lanu o lo gbo be oun ri O soro falejo, ko to mo s’are akura. Won lo jekun, o lo jekun, ona ofun re si ndun jikun jikun. Yangi ni ti oun o fi baye oko je, erin ni oun o mari. Ori ti yoo supo, oni je ki alaisan oye. Ailaso lorun paka, oto apero omo eriwo. • • • • • • • • • • • • • • • • • • • Ololo to lohun o lolu Oyo gbo, Agbara ni ngbe egungun re kiri yi. Eruko lori igi aka, Erugogo lori igi aka, aka nikan ni igi ti nbe ninu igbo ni Igbin kaa, ekiti kaa, ebiti ti ko gboju ole pa gbin. Munu seka, modle s’oto, bope titi oun ti bini ko ni sai bini. Iku lo sokolobinrin dapon. Oro ti o to okoo ni baagba je Ogomope to lohun o korun gbongbon, e pe ko wehin wo awo igbago to fi denu kole. Idi aro la sinku aso, idi ikoko la sinku ogi. Oro ta di sinu ewe gbodogi ti o mi, to ba denu ewe koko yo faya. Beyan o da yagan senu, o ye ko so pako sehin. A le ti tori wipe a pe, ka pada lona. Ti nkan eni ba sonu ama loju eni ti wuni ko ri he. Adete soro meji o fi kan paro, oni oun ki lese, oun ti ya ni ekan na. Badiye okoko ba ye sibi ti o to, eyin re o sofo. Eni ti ko fe yawo, ana ki kun fun. Omode to ba ni ara johun go, baba re l’onbu. Eti lawoko fi ngbeyawo oro. Oun ti a ba fun ole pamo, ole kii ji. Nkan ti ako mo je ni anwo tegbin tegbin, bi aba mo imi je bi oyun ni yori. Bi are ko ba to are aki powe, bi oro ko ba to oro ako gbodo fi itan • • • • • • • • • • • • • • • • • • bale, bi ise ko bale aki bowe ti, Bi oro ko ba tobi akawe re kii po. • • • Ise ki je ise eni ka fowo go. Bi omo eni ko ba gbon aki sa l’ohun. Ki a dara die ki ato sawure ni awon fin je okunrin ti ko ba dara tin se awure obinrin ko leri. Eru ikun ni afi ngbe t’ode. Agba ti ko lese nle ama logbon ninu. Ile ti pa eruwa da, odi egbe iganganran Koji kowi ki polohun se lohun. Bi babalawo ba jagbon ese bibu, ole j’agbon inu omi bibalo. Agbon se oyin se, oju oloko kowulasan. Bi ifa ba teni tan se ni antun ara eni te. Abiku aye saso, torun ka. Otan lowo onile alejo dahun. Itakun to ba takun bi anamo, ko le dun bi anamo. Atunranmu ni ja ekun. Afada pakun e rora se, eniyan lo fese te ehoro pa. Eni ba sun laaji, enikan ki ji apiroro. Oye niyoo kilo fohun tobi, ebi ni yo soro f’ole. Alabahun bokele, omo re yanu o lo gbo be oun ri. Bi itakun lapa lese ko gbodo lepa erin. Awodi ki pa lili, aja ko gbodo peja inu omi. • • • • • • • • • • • • • • • • • • • Orun ki ri se loganjo, afi loju momo. Gbogbo atelewo lo darijo fode sokan, a mo nto se atampako to fi ya tie loto. Somi ki ngberu leye ijebu nke. Oun to ba wuni nipo lola eni, ologun eru ku, aso re je ikansoso. Ojo oru ko peni rere, bi ko ba olosa, a peke, a si pa fenifeni Ojojo nse iwofa, won lo ko ise re de, to ba somo olowo won a ni ko roju f’ata senu. Ojo pa werepe deni akolu, ere ba edun nile o d’ole. Oju imole ko kuro loti, obimo oso ni imoru. Oju ki pon edun ko di eni ile. Oko nla se alangba pinsin, eni to ju ni lo nse ni. Oku ajanaku la yo ada, ta ni je yo agada loju erin. Okunrin to ba fe ku, ko mo ba aye alapa je, ko mo so wipe omitoro eja koro. Olokunrun to’ pe laye, apenu lo pe. Olowo pe ilu, talika ko jo, ojo wo lo ma rowo pe tire. Omi nsan nidi ogede, ogede nsunkun omi. Ona mi ko dun mi, ko le jo arafifo. Oni, agemo ku si aaro onile, ola agemo ku saro onile, bi oju ko ba ti onile, oye ki oju ti agemo. Eni kansoso, kii sigun. Ookan ni won n’ta esin lorun, sugbon ori re ni onibode n’gba. • • • • • • • • • • • • • • • • • • • • • • Oore wo lorisa se fun abuke, to bimo to soo ni orisagbemi. Ori adetu npete aran, ori adaran n p’ete ati j’oba. Ori obinrin kii buru ko ma ni iyako, bi ko ni laye a ni lorun. Orogun iya re d’aso fun o onyanbo, osese ni iya re ko da fun o. Eni ba pa ogongo ti o ti iya re mole, Bi o ba rowo se eran nanma, yo yo ibon si baba re. Baa se yawo, Baa joye, igbawo l’eran o dara lori iresi. Ile yio gbobi, ile yi o gba koko, yoo saa gba emi ni moni. Oju lo pon apon to bi d’aba abiku. Eni ti o se ado mo oke to nleri, awon to nfi ojoojumo s’ode ekun paje se ki won fa aso ya mo iba lorun ni. Daopo loro, pale lo binrin oku, ko petu, ko jetu orin, ode ti n’fi aso funfun degbo. Eni taato laa gan aganran a ma gan oloko. Witemi demi, Baba taa ni wi teni deni (oju korokoro, ki poju korokoro je) Ihale doko ogbon ebe, to ni bi won ba de sale oko, ki won o kesi ohun. Ka rado ka sun, emi la fe kara ile o mi (Gbigbekele eniyan ki o ma si fakoyo). Omo to ba su imikimi, ewe esisi la fi nu die. Omo to bu iya re lehin sa, ko si alagbapon to je pon on. Omuti t’oun were egbera ni. Oran ki ba ni, ko ma fi aye ope si, ti ori eni ba pa, afi a hu irungbon • • • • • • • • • • • • • di. • • • • Oro dun mi ju oloro, oloro ku sile, lagbejo ro ku sita. Osupa ko mo ode olosi, bo dele oloro asi d’ele eru. Pa pa pa la soro ipa. Pasan meje la ja fagogo, okansoso la sese fi na yi, oni ara n kan oun gogo, bee ara re ni mefa joki mbo. Pele larewa nrin, jeje lomo oba nyan. Sin mi ka re le ana, lo gbe ewu etu wo, ki loko iyawo yoo wo lo. Saka ta para ni agbalagba nbeto, to ba nfa lolo, warapa mbo nhun. Ta laba fi iya lo, lehin alapa masise. Ti ako ba da aso le aso aki pe ikan lekisa. Tete popo ti lomi tele ki ojo to ro si. Talaasi loun o ba o gbe omi ko si aye, gongo imu re nko. Wiwi ni ti onile, kiko ni ti alejo, ti onile ba ni ki a je tan, alejo a ni ki a je ku. Won gangan won gangan ko leyin, die ni eyin tin je eran, iyoku ki ereke ma baa papo ni. Beru ba pe nile, a ma fi alajobi bura. Apata paara pa ara le ni ajuba, oku eni ti yoo ko. Orisa ki gba meji lowo imele, bo ba gba apa asi fun ni enu Ojo pon mi f’ole, ko segi fun. Oromodie fo puru, won ni eran lo, se ko mo t’ile waye ni. Orule bo aja mole, aso bo ese idi. • • • • • • • • • • • • • • • • • • • • • • • • • • • • Onspa le eni ko le re, eni owo re ba to k’olo tun se. Otito doja o kuta, owo lowo ni won ra eke. Oto gee ni igbehin ore, ki lo se fun mi ni gbeyin ale. Owo ibon ko to owo etu, ojo kan la ra ibon, ojo gbogbo la ra etu. Owo nini ni omo mi mo akara je. Owo ti ko ba le dani ni gbese, ko le lani. Owu asiwere ko rugba re woja, awon ara ile re ni oje. Oye enigbogbo ko sope isu jinna, ko ye alubata. Oba ki mu eje, iyi loba nfi ori bibe se. Obe ahun ni afi npa ahun, eni ba yo ida, yoo ti pa ida subu. Obe nwo ile ara re, Oni ohun ba akoja. Obo ko si n idere mo, okansoso to ku aso aran lofi nbora. O duni oku m’erin, emi o ku m’efon, odun meta oni, oke m’eku eliri, olanrewaju in tabi ola nrehin. Okanjuwa eniyan ni nje Bamgbose, iwonba ti a ba le gbe ninu ose la ngbe. Ole so oko di odo, oni toun ba jalu wii, oun o pa oko lo bii rere. Omode bu iroko o boju wehin, o ro pe lesekanna ni oluwere maa npa won ni. Omo eni ki se idi bebere, ka fi ileke si didi elomiran. Omo k’eyin ogba egbon, omo taye otawon yo. Omo oku ni o, yoo ye ni, dandan ni ka ki iya re ku ewu. Bi aja ba wo aso ina, ti amotekun wo ewu eje, ti ologinni si san akisa • • • • • • • mo idi, sibe sibe egbe aperan je nii se. • Bi ile kan ile, ti odede kan odede, bi a ko ba fe ni ni be a kii to abere, eni ti a ba fe ni ga to erin loju eni. Eniyan ti ko ba sayan kii yan. Ewo lo san ninu omo Bankale, okan nje eeru, ekeji nje iyepe. Eni ti ko gbo tenu ega, ni nso pega npatoto. Ibon ni apati ibon ko ni apati, ko seni to fe ki a doju ibon ko oun. Igba omode sonu, oni ohun fi ami si, o sa digba ti o ba ri igba ohun ko to ri ami. Ijapa nre ajo, won ni ijo wo ni yoo de, oni odi ijo ti oun ba te koun to pada. Ikamudu n difa, akit n rubo, asin n wure, e tun nsope kini kan n run, ara ta ni mo ninu gbogbo won. Iku wole ahoro lasan, ofo to se eni ti ko ni nkan. Won ni karugbo ponmo sehin, oni ohun ko leyin, se ami ko paje ni. Iya meta nti arinde-oru, o subu, o fowo ba imi, o fe fi run imu, ofi bo enu. Iya nje agbale oja, aja jehun ko kewe. Iyawo di meji, inu oko di odo. Jeki nfi idi he, ni alejo fi ti onile sode. Jo mi, omo jomi omo, onroro nii so ni da. Keni yo ma yo, keni ebi npa ma bara je, ebi nbe leyin ayo, ayo sin be lehin ebi. Kaku lomode ka fi esin se itele osan ju ki a ku lagba laini adiye irana • • • • • • • • • • • • • • • • lo. • • • • • • • • Kini igun se ti obo ko se, igun pa lori, obo pa nidi. Ki ni apari nwa niso oni gbajamo. Ki I se ejo eleyin gangan, orisa to da eyin fun, ni ko fi awo boo. Kokoro to jefo jare efo, iwonba ni eweko daramo. Maalu to je ebu loni ka lu Fulani. Mariwo to loun o kan orun, igbago a d’ese lotobi. Meji lo we, bi ko ya, yoo. Melo melo laa so iso oja, die ni so oniru, die niso ologiri, Bi o ba so niso alaso esinsin a tu ofo. Mee waye ejo fomo re foko meta, to bat un maa waye ejo nko. Mose lasi ekun aja ko gbodo de ibe kiniun. Nhun o gun iya fun oje, n’ibi esun isu laa ti mo. Nigba wo ni maku ko ni ku, maku ko mayo o nbu opa, maku ko mo iwe, onmookun lodo, makun ko logun egbe lowo onfi okun ogede gun ope. Nitori aditi ni ojo se usu, nitori afoju lo se nku. Obi bo lowo alakedun, oni oun fun ara ite bi ko ba fun ara ile nko, yoo sokale wa mu bi. Obuko ni aisan olowo oun ba oun leru, boba san a ni oun f’obuko oun wewu amodi, boba si ku, awon omo re lawon o pa fi sinku. Ogun kip o ka pin fun ero iworan. Ohun owo pa ti ko ku, ona orun ni ko mo. Ohun ti aja ri ti ofi ngbo, ko to eyi ti aguntan ri to fi nse iranwo. • • • • • • • • • • • Ohun tin se lemboye ki ase omo re, lemboye nsunkun owo, omo re nsunkun oko. Ohun ti o gbaso lara onile, l’ofi abebe le alejo lowo. Okan roro nru, o ja ofon lekennina. Aki soro ori bibe loju omode, lorun lorun ni yoo ma wo ni. Eni ti o loyun Fulani, funfun ni yoo fi bi. Omo ti o ba gbe enu agba sonu, bi won ba r’oko, won ki le ro dele. Ba diye okoko ba ye sibi ti o to, eyin re o sofo. Gberi o de ki wo apo, aparun ki wo agbon, ijo ti gberi ati aparun ba wo agbon won n sipa ode ni. Ona ofun ko ni gbongbo, bi ba nbo, komogbo, onitohun soro re lenu ni. B’awa o tito onije a binu, b’eyin o ti mo oni je eni suru. Amuni seni ni lemomu ti ile re n’jo, ti nsare ko mosalasi. Sango payan dede mo, oya ni nfategu ka paanu eyan. Eni ti ko fe iyawo ana ki ku fun. Oun ti a fun ole pamo, ole kii ji. Nkan ti a ko mo je ni a wo tegbin tegbin, bi a ba mo imin je, bi oyin ni yoori. Bi are ko ba to are a kii pa owe, bi oro ko ba to oro ako gbodo fitan bale, bi ise ko ba bale aki bowe tii, Bi oro kobatobi akawe kipo, ise ki je ise eni ka fowo go. Bi omo eni ko bag bon, a ki sa lohun Ki a dara die ki a to sawure ni awure fi nje, okunrin ti ko ba dara tin • • • • • • • • • • • • • • • • • se awure, obinrin ko le ri. • • • • • • • • • • • • • • • • • • • • • Eru ikun ni a fi ngbe tode. Agba ti ko lese nle ama logbon ninu. Ile ti pa ewure da, o di egbe iganganran. Koji kowi ki polohun se lohun. Bi babalowo ba jagbon ese bibu, ole a jagbon inu omi bibalo. Agbon se, oyin se, oju oloko ko wu lasan. Abese tirin mo jo, ko mo jo, baba re lo pelu. Ko to ise lowo ike, aerwa ni pa. Bi ifa ba te ni tan, se ni a tun ara eni te. Abiku aye saso, torun ka. Itakun to ba takun bi anamo, koledi bi anamo Atunramu ija ekun. Afada pakun e ro ra se, eniyan lo fese te ehoro pa. Eni ba sun laaji, enikan ki ji apiroro. Oye ni kilo foni tobi, ebi ni soro f’ole. Alabahun bokele, omo re yanu, o lo gbo be oun ri. Bi itakun tapa lese ko gbo lepa erin. Awodi ki pa lili, aja ko gbodo peja inu omi. Elulu to fa ojo, ori ara re ni yorole. Ojo oganjo pelewu eta ko d’ele wi. Eje a mo w obo, omode to so aja re niki tagba mose. • • • • • • • • • • Asebaje se bi toun la n wi, Aseburuku e ku ara fun. Iya ni t’opa, opa pa ejo laije. Oyeni gbogbo ko yowo aro, ko ye at’ole Akin ku, eta ruu, ikamudun ko fe, e tun pe nkan nrun. Omode ti n fi igba muko, to ba dagba tan tagiri oni ka lenu mo. Oun ti a ko je lenu ki run lona ofun eni. Ai foro sawani, oro a gbe oluwa re lo. Omo ti yoo sin iya sin Baba kii gbo sise okere. Aki rin l’orun ka he agilinti, Olorun Oba ni fun ni. Eku to fi ako s’ile tin je obe, t’enu eni lo fe gbo. Agbejoro ati Onkowe Sikiru Adewoye


Comments

Copyright © 2024 UPDOCS Inc.